Ékísódù 7:21 BMY

21 Ẹja inú odò Náìlì sì kú, odò náà ń rùn gidigidi tí ó fi jẹ́ pé àwọn ará Éjíbítì kò le è mu omi inú rẹ̀. Ẹ̀jẹ̀ sì wà ni ibi gbogbo ni ilẹ̀ Éjíbítì.

Ka pipe ipin Ékísódù 7

Wo Ékísódù 7:21 ni o tọ