Ékísódù 7:22 BMY

22 Ṣùgbọ́n àwọn apidán ilẹ̀ Éjíbítì sì ṣe bákan náà pẹ̀lú agbára òkùnkùn wọn, ọkàn Fáráò sì yigbì ṣíbẹ̀ kò sì fetí sí wọn gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti sọ.

Ka pipe ipin Ékísódù 7

Wo Ékísódù 7:22 ni o tọ