Ékísódù 9:35 BMY

35 Ọkàn Fáráò sì yigbì, kò sì jẹ́ kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ó lọ, bí Olúwa ti sọ láti ẹnu Mósè.

Ka pipe ipin Ékísódù 9

Wo Ékísódù 9:35 ni o tọ