Ẹ́sítà 1:12 BMY

12 Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn ìránṣẹ́ jẹ́ iṣẹ́ ọba, ayaba Fásítì kọ̀ láti wá. Nígbà náà ni ọba bínú gidgidi, ìbínú náà sì pọ̀ jọjọ.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 1

Wo Ẹ́sítà 1:12 ni o tọ