Ẹ́sítà 1:13 BMY

13 Gẹ́gẹ́ bí ìṣe rẹ̀ ní ìgbà gbogbo, ọba máa ń béèrè ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ àwọn tí ó ní ìmọ̀ òfin àti ìdájọ́, ó sọ ọ́ fún àwọn amòye tí wọ́n mòye àkókò,

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 1

Wo Ẹ́sítà 1:13 ni o tọ