Ẹ́sítà 2:16 BMY

16 A mú Ésítà lọ síwájú ọba Ṣéríṣésì ní ibùgbé ọba ní oṣù kẹ́wàá, tí ó jẹ́ oṣù Tébétì, ní ọdún kéje ìjọba rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 2

Wo Ẹ́sítà 2:16 ni o tọ