Ẹ́sítà 2:17 BMY

17 Ésítà sì wu ọba ju àwọn obìnrin tó kù lọ, Ó sì rí ojú rere àti oore ọ̀fẹ́ gbà ju ti àwọn wúndíá tó kù lọ. Nítorí náà ó fi adé ọba dé e ní orí ó sì fi ṣe ayaba dípò Fásítì.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 2

Wo Ẹ́sítà 2:17 ni o tọ