Ẹ́sítà 2:18 BMY

18 Ọba sì se àsè ńlá, àsè Ésítà, fún gbogbo àwọn ọlọ́lá àti àwọn ìjòyè e rẹ̀. Ó sì kéde ìsinmi jákèjádò ìgbéríko ó sì pín ẹ̀bùn fún wọn pẹ̀lú bí ọba ṣe lawọ́ tó.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 2

Wo Ẹ́sítà 2:18 ni o tọ