Ẹ́sítà 2:22 BMY

22 Ṣùgbọ́n Módékáì sì mọ̀ nípa ọ̀tẹ̀ náà, ó sọ̀ fún ayaba Ẹ́sítà, Ẹ́sítà sì sọ fún ọba, wọ́n sì fi ọlá fún Módékáì.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 2

Wo Ẹ́sítà 2:22 ni o tọ