Ẹ́sítà 2:23 BMY

23 Nígbà tí wọ́n sì wádìí ọ̀rọ̀ náà tí ó sì já sí òtítọ́, a sì ṣo àwọn ìjòyè méjèèjì náà kọ́. Gbogbo nǹkan wọ̀nyí ni a kọ sínú ìwé ìtàn ní iwáju ọba.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 2

Wo Ẹ́sítà 2:23 ni o tọ