Ẹ́sítà 3:1 BMY

1 Lẹ́yìn àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nyí, ọba Ṣérísésì dá Hámánì ọmọ Hámádátà, ará a Ágágì lọ́lá, ọba gbé e ga, ó si fún un ní àga ọlá tí ó ju ti gbogbo àwọn ọlọ́lá tó kù lọ.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 3

Wo Ẹ́sítà 3:1 ni o tọ