Ẹ́sítà 4:13 BMY

13 Ó sì rán ìdáhùn yí sí i pé; “Má ṣe rò pé nítorí pé ìwọ wà nílé ọba ìwọ nìkan lè yọ láàrin gbogbo àwọn Júù.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 4

Wo Ẹ́sítà 4:13 ni o tọ