Ẹ́sítà 4:14 BMY

14 Nítorí bí ìwọ bá dákẹ́ ní àkókò yìí, ìrànlọ́wọ́ àti ìtúsílẹ̀ fún àwọn Júù yóò dìde láti ibòmíràn, Ṣùgbọ́n ìwọ àti àwọn ìdílée bàbá à rẹ yóò ṣègbé. Taa ni ó mọ̀ wí pé nítorí irú àkókò yìí ni o ṣe wà ní ipò ayaba?”

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 4

Wo Ẹ́sítà 4:14 ni o tọ