Ẹ́sítà 6:2 BMY

2 Wọ́n rí àkọsílẹ̀ níbẹ̀ pé Módékáì tí sọ àṣírí Bígítanà àti Térésì, àwọn ìjòyè ọba méjì tí wọ́n ń ṣọ́ ẹnu ọ̀nà, tí wọ́n ń gbérò láti pa ọba Ṣérísésì.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 6

Wo Ẹ́sítà 6:2 ni o tọ