Ẹ́sítà 8:3 BMY

3 Ẹ́sítà sì tún bẹ ọba lórí ìkúnlẹ̀, pẹ̀lú omijé lójú. Ó bẹ̀ẹ́ kí ó fi òpin sí ètò búburú Hámánì ará Ágágì, èyí tí ó ti pète fún àwọn Júù.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 8

Wo Ẹ́sítà 8:3 ni o tọ