Ẹ́sítà 8:2 BMY

2 Ọba sì bọ́ òrùka dídán an rẹ̀, èyí tí ó ti gbà lọ́wọ́ọ Hámánì ó sì fi fún Módékáì, Ẹ́sítà sì yàn án gẹ́gẹ́ bí olóórí ilée Hámánì.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 8

Wo Ẹ́sítà 8:2 ni o tọ