Ẹ́sítà 8:1 BMY

1 Ní ọjọ́ kan náà ni ọba Ṣérísésì fún Ésítà ayaba ní ilée Hámánì, ọ̀ta àwọn Júù. Módékáì sì wá síwájú ọba, nítorí Ẹ́sítà ti sọ bí ó ṣe jẹ́ sí ọba.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 8

Wo Ẹ́sítà 8:1 ni o tọ