Ẹ́sítà 9:30 BMY

30 Módékáì sì kọ ìwé ránsẹ́ sí gbogbo àwọn Júù, sí ìgbéríko mẹ́tadínláàdóje (127) ní ilé ọba Ṣéríṣésì ní ọ̀rọ̀ àlàáfíà àti ìfọ̀kànbalẹ̀

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 9

Wo Ẹ́sítà 9:30 ni o tọ