Ẹ́sítà 9:31 BMY

31 Láti fi ìdí àwọn ọjọ́ọ Púrímù yìí múlẹ̀ ní àkókò tí wọ́n yàn, gẹ́gẹ́ bí Módékáì àti Ẹ́sítà ayaba ti pa á láṣẹ fún wọn, àti bí wọ́n ṣe fi lélẹ̀ fún ara wọn àti irú àwọn ọmọ wọn ní ìbámu pẹ̀lú àkókò ààwẹ̀ àti ẹkún un wọn.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 9

Wo Ẹ́sítà 9:31 ni o tọ