Ẹ́sítà 9:4 BMY

4 Módékáì sì jẹ́ ẹni pàtàkì ní ààfin, òkìkíi rẹ̀ sì tàn jákè jádò àwọn ìgbéríko, ó sì ní agbára kún agbára.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 9

Wo Ẹ́sítà 9:4 ni o tọ