Ẹ́sítà 9:5 BMY

5 Àwọn Júù sì gé gbogbo àwọn ọ̀tá a wọn lulẹ̀ pẹ̀lú idà, wọ́n pa wọ́n, wọ́n sì run wọ́n, wọ́n sì ṣe ohun tí ó wù wọ́n sí àwọn tí ó kóòríra wọn.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 9

Wo Ẹ́sítà 9:5 ni o tọ