Hósíà 10:11 BMY

11 Éfúráímù jẹ́ ọmọ màlúù tí atí kọ́, to si fẹ́ràn láti máa pa ọkàlórí ọrun rẹ̀ tó lẹ́wà nièmi ó dí ẹru wúwo léÈmi yóò mú kí a gun Éfúráímù bí ẹṣinJúdà yóò tú ilẹ̀,Jákọ́bù yóò sì fọ́ ogúlùtu rẹ̀

Ka pipe ipin Hósíà 10

Wo Hósíà 10:11 ni o tọ