Hósíà 10:12 BMY

12 Ẹ gbin òdòdó fún ara yínkí ẹ sì ká èso ìfẹ́ àìlópin,Ẹ tu ilẹ̀ yín tí a kòronítorí pé ó ti tó àsìkò láti wá Olúwa,títí tí yóò fi dé,tí yóò sì rọ òjò òdodo lé yín lórí.

Ka pipe ipin Hósíà 10

Wo Hósíà 10:12 ni o tọ