Hósíà 10:4 BMY

4 Wọ́n ṣe ìlérí púpọ̀,wọ́n ṣe ìbúra èké,wọ́n da májẹ̀mú:báyìí ni ìdájọ́ hù sókè bí igi ìwọ̀ ni aporo oko,bi i koríko májèlé láàrin oko tí a ro.

Ka pipe ipin Hósíà 10

Wo Hósíà 10:4 ni o tọ