Hósíà 10:5 BMY

5 Àwọn ènìyàn tí ń gbé Samáríàbẹ̀rù nítorí ere màlúù tó wà ní Bẹti-Áfẹ́nìÀwọn ènìyàn rẹ̀ yóò ṣọ̀fọ̀ le e lóríbẹ́ẹ̀ ni àwọn àlùfáà abọ̀rìṣà rẹ̀Gbogbo àwọn tó láyọ̀ sì dídán rẹ̀,nítorí ogo rẹ̀ nítorí o tí lọ kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Hósíà 10

Wo Hósíà 10:5 ni o tọ