Hósíà 13:1 BMY

1 Nígbà Éfúráímù bá ń ṣọ̀rọ̀, àwọn ènìyàn máa ń wárìrì,a gbé e ga ní Ísírẹ́lìṣùgbọ́n ó jẹ̀bi ẹ̀ṣùn pé ó ń sin òrìṣà Báálì, ó sì kú.

Ka pipe ipin Hósíà 13

Wo Hósíà 13:1 ni o tọ