Hósíà 13:2 BMY

2 Báyìí, wọ́n ń dá ẹ̀ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀wọn fi fàdákà ṣe ère òrìṣà fúnra wọnère tí a fi ọgbọ́n dá àrà sígbogbo wọn jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ oníṣọ̀nàWọn ń sọ nípa àwọn ènìyànwọ̀nyí. Pé, Jẹ́ kí àwọn“Ènìyàn tí ń rúbọ fi ẹnuko àwọn màluu ni ẹnu.”

Ka pipe ipin Hósíà 13

Wo Hósíà 13:2 ni o tọ