Hósíà 3:4 BMY

4 Nítorí pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yóò wà fún ọjọ́ pípẹ́ láì ní ọba tàbí olórí, láìsí ìrúbọ tàbí pẹpẹ mímọ́ láìsí àlùfáà tàbí òrìṣà kankan.

Ka pipe ipin Hósíà 3

Wo Hósíà 3:4 ni o tọ