Hósíà 4:12 BMY

12 Wọ́n ń gba ìmọ̀ràn lọ́wọ́ ère igiỌ̀pá igi sì ń dá wọn lóhùn.Ẹ̀mí àgbèrè ti mú wọn sìnàwọ́n sì jẹ́ aláìṣòótọ́ sí Ọlọ́run wọn.

Ka pipe ipin Hósíà 4

Wo Hósíà 4:12 ni o tọ