Hósíà 4:13 BMY

13 Wọ́n ń rúbọ lórí àwọn òkè ńlá,Wọ́n sì ń sun ọrẹ tùràrí lórí àwọn òkè kékeréLábẹ́ igi óákù, àti igi pópúlárìàti igi ẹlimuati onírúurú igi tí ìbòjú rẹ̀ dáraNítorí náà àwọn ọmọbìnrin yín yóò ṣe àgbèrèàti àwọn àfẹ́sọ́nà yín yóò ṣe àgbèrè.

Ka pipe ipin Hósíà 4

Wo Hósíà 4:13 ni o tọ