Hósíà 4:14 BMY

14 “Èmi kò ní jẹ àwọn ọmọbìnrin yínníyà nígbà tí wọ́n bá ṣe àgbèrètàbí àwọn àfẹ́sọ́nà ọmọ yín,nígbà tí wọ́n bá ṣe àgbèrènítorí pé àwọn ọkùnrin pàápàá ń bá alágbèrè kẹ́gbẹ́.Wọ́n sì ń rúbọ pẹ̀lú àwọn alágbèrè ilé òrìṣà.Nítorí náà, ènìyàn tí kò bá ní òye yóò parun!

Ka pipe ipin Hósíà 4

Wo Hósíà 4:14 ni o tọ