Hósíà 4:15 BMY

15 “Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé o ṣe àgbèrè ìwọ Ísírẹ́lìÌdájọ́ yìí wà fún un yín Ẹ má ṣe jẹ́ kí Júdà di ẹlẹ́bi.“Ẹ má ṣe lọ sí Gílígálì.Ẹ má sì ṣe gòkè lọ sí Bẹti-ÁfénìẸ má sì búra pé, ‘Bí Olúwa ti wà láàyè nítòótọ́!’

Ka pipe ipin Hósíà 4

Wo Hósíà 4:15 ni o tọ