Hósíà 7:11 BMY

11 “Éfúráímù dàbí àdàbàtó rọrùn láti tàn jẹ àti aláìgbọ́ntó wá ń pé Éjíbítì nísinsìn yìító sì tún ń padà lọ si Ásíríà.

Ka pipe ipin Hósíà 7

Wo Hósíà 7:11 ni o tọ