Jóṣúà 1:1 BMY

1 Lẹ́yìn ikú u Móṣè ìránṣẹ́ Olúwa, Olúwa sọ fún Jóṣúà ọmọ Núnì, olùrànlọ́wọ́ ọ Móṣè:

Ka pipe ipin Jóṣúà 1

Wo Jóṣúà 1:1 ni o tọ