Jóṣúà 1:15 BMY

15 títí Olúwa yóò fi fún wọn ní ìsinmi, gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe fún un yín, àti títí tí àwọn pẹ̀lú yóò fi gba ilẹ̀ náà tí Olúwa Ọlọ́run yín fi fún wọn. Lẹ́yìn náà, ẹ̀yin lè padà sí ilẹ̀ ìní in yín, tí Mósè ìránṣẹ́ Olúwa fi fún un yin, ní agbégbé ìlà-óòrùn ti Jọ́dánì.”

Ka pipe ipin Jóṣúà 1

Wo Jóṣúà 1:15 ni o tọ