Jóṣúà 10:21 BMY

21 Gbogbo àwọn ọmọ ogun sì padà sí ọ̀dọ̀ Jóṣúà ní ibùdó ogun ní Mákédà ní àlàáfíà, kò sí àwọn tí ó dábàá láti tún kọlu Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Jóṣúà 10

Wo Jóṣúà 10:21 ni o tọ