Jóṣúà 10:31 BMY

31 Nígbà náà ni Jóṣúà àti gbogbo ará Ísírẹ́lì, tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ kọjá láti Líbínà lọ sí Lákíṣì; ó sì dótì í, ó sì kọlù ú.

Ka pipe ipin Jóṣúà 10

Wo Jóṣúà 10:31 ni o tọ