Jóṣúà 10:38 BMY

38 Nígbà náà ni Jóṣúà àti gbogbo Ísírẹ́lì tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ yí padà, wọ́n sì kọlu Débírì.

Ka pipe ipin Jóṣúà 10

Wo Jóṣúà 10:38 ni o tọ