Jóṣúà 11:12 BMY

12 Jóṣúà sì kó gbogbo àwọn ìlú ọba àti ọba wọn, ó sì fi idà pa wọ́n. Ó sì run gbogbo wọn, gẹ́gẹ́ bí Mósè ìránṣẹ́ Olúwa ti pàṣẹ.

Ka pipe ipin Jóṣúà 11

Wo Jóṣúà 11:12 ni o tọ