Jóṣúà 11:4 BMY

4 Wọ́n sì jáde pẹ̀lú gbogbo ogun wọn àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹsin àti kẹ̀kẹ́ ogun ńlá, wọ́n sì pọ̀, gẹ́gẹ́ bí iyanrìn etí òkun

Ka pipe ipin Jóṣúà 11

Wo Jóṣúà 11:4 ni o tọ