Jóṣúà 14:11 BMY

11 Síbẹ̀ èmi ní agbára lónìí, bí ìgbà tí Mósè rán mi jáde. Èmi sì ní agbára láti jáde fún ogun nísinsìnyí gẹ́gẹ́ bí mo ti wà ní ígbà náà.

Ka pipe ipin Jóṣúà 14

Wo Jóṣúà 14:11 ni o tọ