20 Èyí ni ilẹ̀ ini ẹ̀yà àwọn ọmọ Júdà gẹ́gẹ́ bi ìdílé wọn.
21 Ìlú ìpẹ̀kun gúsù ti ẹ̀yà Júdà ní Négéfi ní ààlà Édómù niwọ̀nyí:Kabísélì, Édérì, Jágúrì,
22 Kínà, Dímónà, Ádádà,
23 Kédéṣì, Hásórì, Ítina,
24 Sífì, Télémù, Bíálótì,
25 Hasori-Hádátà, Kerioti-Hésírónì (tí í ṣe Hásórì),
26 Ámámù, Sẹ́mà, Móládà,