40 Kábónì, Lámásì, Kítílísì,
41 Gédérótì, Bẹti-Dágónì, Náámà àti Mákédà, ìlú mẹ́rìndín ní ogún àti ìletò wọn.
42 Líbínà, Étíérì, Áṣánì,
43 Hífítà, Ásínà, Nésíbù,
44 Kéílà, Ákísíbì àti Máréṣà, ìlú mẹ́sàn àti àwọn ìletò wọn. (9)
45 Ékírónì, pẹ̀lú ibùgbé àti àwọn ìletò rẹ̀ tó yí i ká,
46 ìwọ̀-oòrùn Ékírónì, gbogbo èyí tí ń bẹ nítòòsí Áṣídódù, pẹ̀lú àwọn ìletò wọn,