Jóṣúà 16:9 BMY

9 Ó tún mú àwọn ìlú àti ìletò wọn tí ó yà sọ́tọ̀ fún àwọn ọmọ Éfúráímù tí ó wà ní àárin ìní àwọn ọmọ Mánásè.

Ka pipe ipin Jóṣúà 16

Wo Jóṣúà 16:9 ni o tọ