Jóṣúà 17:3 BMY

3 Nísinsìn yìí Sẹloféádì ọmọ Héférì, ọmọ Gílíádì, ọmọ Mákírì, ọmọ Mánásè, kò ní ọmọkùnrin, bí kò se àwọn ọmọbìnrin, tí orúkọ wọn jẹ́: Málà, Nóà, Hógílà, Mílíkà àti Tásà.

Ka pipe ipin Jóṣúà 17

Wo Jóṣúà 17:3 ni o tọ