1 Gègé kéjì jáde fún ẹ̀yà Símíónì, ní agbo ilé, ní agbo ilé. Ìní wọn sì wà ní àárin ilẹ̀ Júdà.
2 Lára ìpín wọn ní:Béérí Ṣébà (tàbí Ṣẹ́bà), Móládà,
3 Hasari-Ṣúálì, Báláhì, Ésémù,
4 Élítóládì, Bétúlì, Hómà,
5 síkílágì, Bẹti-Mákábótì, Hasari-Súsà,
6 Bẹti-Lébà ati Ṣárúẹ́nì, ìlú wọn jẹ́ mẹ́talá àti ìletò wọn.