2 Lára ìpín wọn ní:Béérí Ṣébà (tàbí Ṣẹ́bà), Móládà,
3 Hasari-Ṣúálì, Báláhì, Ésémù,
4 Élítóládì, Bétúlì, Hómà,
5 síkílágì, Bẹti-Mákábótì, Hasari-Súsà,
6 Bẹti-Lébà ati Ṣárúẹ́nì, ìlú wọn jẹ́ mẹ́talá àti ìletò wọn.
7 Háínì, Rímónì, Étérì àti Áṣánì: Ìlú wọn jẹ́ mẹ́rin àti ìletò wọn:
8 Àti gbogbo àwọn agbégbé ìlú wọ̀nyí títí dé Baalati-Béérì (Rámà ní Négéfì).Èyí ni ìní àwọn ọmọ Símíónì, agbo ilé, ní agbo ilé.