Jóṣúà 2:1 BMY

1 Nígbà náà ni Jóṣúà ọmọ Núnì rán àwọn ayọ́lẹ̀wò méjì jáde ní àsírí láti Ṣítímù. Ó sì wí pé, “Ẹ lọ wo ilẹ̀ náà, pàápàá Jẹ́ríkò.” Wọ́n sì lọ, wọ́n wọ ilé aṣẹ́wó kan, tí à ń pè ní Ráhábù, wọ́n sì dúró síbẹ̀.

Ka pipe ipin Jóṣúà 2

Wo Jóṣúà 2:1 ni o tọ