Jóṣúà 2:11 BMY

11 Bí a ti gbọ́ nǹkan wọ̀nyí; ọkàn an wa pámi, kò sì sí okun kankan fún wa mọ́ nítorí i yín, nítorí pé Olúwa Ọlọ́run yín ni Ọlọ́run ní òkè ọ̀run àti ní ayé.

Ka pipe ipin Jóṣúà 2

Wo Jóṣúà 2:11 ni o tọ