Jóṣúà 2:16 BMY

16 Ó sì ti ṣọ fún wọn pé, “Ẹ lọ sí orí òkè, kí ẹ sì fi ara pamọ́ níbẹ̀ fún ọjọ́ mẹ́ta kí àwọn tí ń lépa yín má baà rí i yín títí tí wọn yóò fi darí. Lẹ́yìn náà kí ẹ máa bá ọ̀nà yín lọ.”

Ka pipe ipin Jóṣúà 2

Wo Jóṣúà 2:16 ni o tọ